Font Size
Numeri 1:47-49
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Numeri 1:47-49
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
47 (A)A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù. 48 Nítorí Olúwa ti sọ fún Mose pé, 49 “Ìwọ kò gbọdọ̀ ka ẹ̀yà Lefi, tàbí kí o kà wọ́n mọ́ àwọn ọmọ Israẹli:
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.