Font Size
Matiu 10:33
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 10:33
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
33 Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá sẹ́ mí níwájú àwọn ènìyàn, òun náà ni èmi náà yóò sọ wí pé n kò mọ̀ níwájú Baba mi ní ọ̀run.
Read full chapter
Luku 12:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 12:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 (A)Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá sẹ́ mi níwájú ènìyàn, a ó sẹ́ ẹ níwájú àwọn angẹli Ọlọ́run.
Read full chapter
1 Johanu 2:28
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Johanu 2:28
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Àwọn ọmọ Ọlọ́run
28 (A)Àti nísinsin yìí, ẹ̀yin ọmọ mi ọ̀wọ́n, ẹ máa gbé inú rẹ̀, pé nígbà tí òun ó bá farahàn, kí a lè ni ìgboyà níwájú rẹ̀, kí ojú má sì tì wá níwájú rẹ̀ ni ìgbà wíwá rẹ̀.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.