Font Size
Johanu 19:35
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 19:35
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
35 (A)Ẹni tí ó rí sì jẹ́rìí, òtítọ́ sì ni ẹ̀rí rẹ̀: ó sì mọ̀ pé òtítọ́ ni òun sọ, kí ẹ̀yin ba à lè gbàgbọ́.
Read full chapter
Johanu 21:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 21:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
24 (A)Èyí ni ọmọ-ẹ̀yìn náà, tí ó jẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí, tí ó sì kọ̀wé nǹkan wọ̀nyí, àwa sì mọ̀ pé, òtítọ́ ni ẹ̀rí rẹ̀.
Read full chapter
1 Johanu 4:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Johanu 4:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
14 (A)Àwa tí rí, a sì jẹ́rìí pé Baba rán Ọmọ rẹ̀ láti jẹ́ Olùgbàlà fún aráyé.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.